Smiley face
Showing posts with label Iroyin. Show all posts
Showing posts with label Iroyin. Show all posts
Wàhálà NURTW: Alh Akanni Olohunwa tí wọ gau!. pt3

Wàhálà NURTW: Alh Akanni Olohunwa tí wọ gau!. pt3

Adé Lawyer, ẹni tó sọ wí pé Alaaji Akanni Olohunwa lo rán òun láti ṣekú pa Kunle Poly kò ti dake àlàyé rẹ. "Kunle Poly là fẹ́ pa, Pine...
Read More
Wàhálà NURTW: Alh Akanni Olohunwa tí wọ gau! pt2

Wàhálà NURTW: Alh Akanni Olohunwa tí wọ gau! pt2

Nígbà tí Ade Lawyer ri wí pé òpin tí de, gbogbo ohun tó pamọ pátá lo ṣàlàyé fun àwọn oniroyin. Alaye ògbólógbòó agbanipa náà ní yìí: "...
Read More
Wàhálà NURTW: Alh Akanni Olohunwa tí wọ gau!

Wàhálà NURTW: Alh Akanni Olohunwa tí wọ gau!

Akíkanjú olopaa ọlọtẹlẹmuyẹ to mú ògbólógbòó ọ̀daràn tí ń jẹ Evans nijosi, Abba Kyari tí mú ọkùnrin kan tí ń jẹ Adeola Williams, ẹni tí inag...
Read More
Ẹ̀jẹ̀ san ni Zamfara: 41 ènìyàn tí wọlẹ̀ sún lójú bajinatu àwọn odaju ẹ̀dá

Ẹ̀jẹ̀ san ni Zamfara: 41 ènìyàn tí wọlẹ̀ sún lójú bajinatu àwọn odaju ẹ̀dá

Ni Ipinle Zamfara, n se ni wọn tẹ òkú àwọn ènìyàn sílè bí ìgbà tí wọn ba le ìṣù sílè loja oritamerin Ibadan. Bi ènìyàn bá dé ijoba ibile Bir...
Read More