Won sin Abubakar Audu lonii ni ilu re, Ogbonicha to wa ni ijoba ibile Ofu ni ipinle Kogi.
Read More
Home / Yoruba
Showing posts with label Yoruba. Show all posts
Showing posts with label Yoruba. Show all posts

E je ka lo dansia lagbo Femi Solar
Faaji n san lagbo Femi Solar nibi ti awon gbajumo ti gbe n je igbaladun orin Jasa to ta lenu. E yin naa le je igbadun re NIBI ...
Read More

"Iyawo mi n yale, o tun bimo ale fun mi": Alabi yari ni kootu Ikorodu
Ogbeni Alabi Rasheed, eni odun mejidinlaadota (48) ti gbe iyawo re, Sherifat, lo si ile ejo lati tu yigi igbeyawo odun mewaa to wa laaar...
Read More

Won gun pasito ijo RCCG lobe niluu Ota
Edward Campbell, eni odun mokandinlaadota (49) ni won ti gbe lo si ile ejo lojo Eti to koja yii pelu esun wi pe o gun pasito Redeemed Ch...
Read More

“Idagbasoke awon akonimoogba gbodo je koko fun NFF” - Amodu
Shuaibu Amodu Shuaibu Amodu, okan lara awon igbimo oludari ajo NFF ti so wi pe ona kan pataki lati se igbelaruge fun ere bo...
Read More
Subscribe to:
Posts
(
Atom
)