Awon foto ayeye isinku Mama HID Awolowo Olayemi Oniroyin 11/28/2015 07:42:00 pm Add Comment Edit Eyi ni die lara awon foto to jade nibi eye ikeyin ti won se fun Mama HID Awolowo eni ti won pada sin lojo karunlelogun osu kokanla odun ... Read More
Se Gbenga Adeboye lo ko Wale Dada nise sorosoro? Olayemi Oniroyin 11/26/2015 12:33:00 pm Add Comment Edit Lori eto Miliki Express lori telifisan Orisun ni won ti gba Adewale Dada TheGood gege bi alejo pataki ni nnkan bi osu meloo kan seyin. Lor... Read More
[Foto] Saheed Osupa Mr Designer Olayemi Oniroyin 11/25/2015 08:04:00 pm Add Comment Edit Awon eniyan oba ni Osupa ti mura tan lati gbe awo orin re tuntun jade. E le ka iroyin naa NIBI . Eniwee, mo sakiyesi wi pe awon aso oke... Read More
Kini ijoba n se nipa awon ti n se ayederu? Olayemi Oniroyin 11/25/2015 07:50:00 pm Add Comment Edit Iroyin yii kii se tuntun, yoo si ti to bi osu kan o le die ti asiri awon to n se ayederu elerindodo Coca Cola ti jade. Sugbon iru awon i... Read More
Atelewo eni ki i tanni i je Olayemi Oniroyin 11/25/2015 10:33:00 am Add Comment Edit #Ogulutu #7 Wole Soyinka A won Yoruba bo, won ni amukun-un eru re wo, o ni oke le n wo, e wole. Ojuse awon obi ki i se lati pes... Read More