Smiley face
Wọn tí fi bàálù gbé òkú Senator Mustapha Bukar padà sile

Wọn tí fi bàálù gbé òkú Senator Mustapha Bukar padà sile

Senator Mustapha Bukar tí parí isẹ rẹ nílùú Abuja. Wọn tí fi bàálù gbé padà sí ìlú rẹ, Katsina. Kí Ọlọ́run Allah bá dárí gbogbo aise dééde ...
Read More
Kositọma dáadáa ní Buhari - Aláké tilẹ Ẹ̀gbá

Kositọma dáadáa ní Buhari - Aláké tilẹ Ẹ̀gbá

"Kositọma dáadáa ní Buhari . Mo fọwọ́ síi kò padà wa nígbà kejì láti wá parí àwọn iṣẹ́ takuntakun tó ti bẹ̀rẹ̀ - Aláké tilẹ Ẹ̀gbá Oba A...
Read More
Oluwo tí ilu Iwo ti padà pelu ara tuntun

Oluwo tí ilu Iwo ti padà pelu ara tuntun

Oluwo tí Ìwọ , Oba Abdul Rasheed Akanbi tún gbéyo pelu ara tuntun nígbà tó dáṣẹ̀ jade láàfin rẹ pẹlu aṣọ onisokoto tiirin. Tí ẹ kò bá gbàgb...
Read More
Ìdìbò kú oṣù mewaa, asofin méjì kú láàárín ọsẹ meji

Ìdìbò kú oṣù mewaa, asofin méjì kú láàárín ọsẹ meji

Lẹ́yìn bí ọsẹ kan tí ọmọ ilẹ̀ igbimo aṣojú sofin n kan kù, Senator míì tún kù ní àárọ̀ òní ni ilu Abuja. Senator Mustapha Bukar to wá láti i...
Read More