Happy Birthday olùkọ́ mi: Apènà pé léèyàn Olayemi Oniroyin 4/12/2018 09:04:00 am Add Comment Edit Ẹ bá ma kí Apena, ẹ bá mi sọ fún olùkọ́ mi wí pé Olayemi mo wọn léèyàn pàtàkì. Bí ó bá lo igba ọdún láyé, ọdún kan ni wọn o fi ka fún ọ lóde... Read More
Òpin àwọn ọmọ Yahoo-yahoo Olayemi Oniroyin 4/12/2018 08:49:00 am Add Comment Edit Ilé táa fitọ́ mọ, ìrì lásán ni ó wo dànù. Joojumọ ni wọn sebi ọlọba. Wọn a náwó bí ẹni wí pé ilẹ̀ ọ̀la kò ní mọ́. Ọ̀pọ̀ tí ń ṣe bigimaanu ló... Read More
Adigunjale wọ Offa, wọn kówó, wọn tún fẹ̀mí ṣòfò Olayemi Oniroyin 4/06/2018 01:14:00 am 1 Comment Edit Àwọn adigunjale wọ ilu Offa lọjọ karùn-ún oṣù kẹrin ọdún yìí láti fọ banki. Àìmọye èmi lo ṣòfò, lára wọn ni ọlọ́pàá àti àwọn obìnrin. ... Read More
Ẹ wo bí wọn se pa àwọn ọmọdé nìpakúpa ni Taraba Olayemi Oniroyin 4/05/2018 01:01:00 pm Add Comment Edit Read More