Smiley face
Ìrántí ọdún kan Moji Olaiya wáyé lẹ́yìn ìsìnkú Aisha Abimbola

Ìrántí ọdún kan Moji Olaiya wáyé lẹ́yìn ìsìnkú Aisha Abimbola

Moji Olaiya tí pé ọdún kan báyìí. Aisha Abimbola lọ ṣẹ̀ṣẹ̀ bẹ̀rẹ̀ ìrìnàjò tiẹ̀ sóde ọ̀run ni. Ta wá ni ènìyàn tí kò ní kú? Àdúrà wa kan ni w...
Read More
Ohun tí Muyiwa Ademola sọ nípa orekelẹwa aya rẹ ni yìí

Ohun tí Muyiwa Ademola sọ nípa orekelẹwa aya rẹ ni yìí

"Olólùfẹ́ mi, aya mi, Akankẹ mi, bí mo bá wà sílè ilé ayé nígbà igba, ìwọ kan náà lọ má jẹ aya mi. Àìmọye ìdùnnú lọ fún mi ti mi ò lé r...
Read More
Oludasilẹ Facebook, Mark Zuckerberg pé ẹni ọdún mẹ́rinlelọgbon (34) lónìí

Oludasilẹ Facebook, Mark Zuckerberg pé ẹni ọdún mẹ́rinlelọgbon (34) lónìí

Òní, 17/05/18, ni ọjọ́ ìbí oludasile Facebook, Mark Zuckerberg, eléyìí tí gbogbo wa njẹ àǹfààní rẹ lónìí. Kí n tó  kí Mark fún ayẹyẹ ọjọ́ ì...
Read More