Abàmì ẹlẹ́dẹ̀ tí dífá fún Super Eagles nípa Russia 2018 Olayemi Oniroyin 6/15/2018 05:51:00 pm Add Comment Edit Ẹlẹ́dẹ̀ abàmì tó sọ àsọtẹ́lẹ̀ nípa wí pé, Donald J. Trump ìlú Amẹrika ni yóò jaye olubori gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ ilẹ̀ Amẹ́ríkà tí kéde wí pé ikọ́ a... Read More
Russia 2018: Pele àti Maradona tí wọlé Olayemi Oniroyin 6/12/2018 07:53:00 am Add Comment Edit Ààrẹ ìlú Russia 🇷🇺, Putin, fún ra rẹ lo kí Pele kaabọ si orile-ede Russia fún igbaradi ìfẹ́ agbaye tí yóò wayé ni or... Read More
"Bukola Sàràkí ni bàbá ìsàlẹ̀ wa" Awọn adigunjale banki Ọfa tí jẹwọ Olayemi Oniroyin 6/03/2018 06:54:00 pm Add Comment Edit Ni olu ileesẹ ọlọ́pàá nílùú Abuja, wọn ti ṣe àfihàn àwọn afurasi adigunjale tí wọn ṣekú pa àìmọye nílùú Offa, Ìpínlẹ̀ Kwara. Àwọn afurasi a... Read More
Dangote kò àádọ́jọ (150) ọkọ̀ kalẹ fún àwon ọlọ́pàá Olayemi Oniroyin 5/31/2018 10:06:00 pm Add Comment Edit Dangote Foundation eléyìí to jẹ àjọ tí Alh Aliko Dangote gbé kalẹ láti lè fi má rán àwùjọ lọ́wọ́ tí pèsè àádọ́jọ (150) ọkọ fún ilé ìṣe ọlọ́p... Read More
Aya Femi Gbajabiamila dira fún ayẹyẹ ọjọ́ ìbí àádọ́ta ọdún Olayemi Oniroyin 5/28/2018 05:37:00 pm Add Comment Edit Adari ọmọ ẹgbẹ́ to pọ̀ jù lọ nílé ìgbìmọ̀ aṣojú sofin Abuja, Femi Gbaja ṣe ajọyọ pẹ̀lú aya rẹ, Yemisi Gbaja, pẹ̀lú bo se pe ẹni àádọ́ta ọdún... Read More