Awon eya kan ti awon opolopo eniyan mo si Egun ti won si maa n pe won ni Egun ti won n gbe ni iwo oorun Naijeria ni won ti yari wi pe asipe ni pipe awon ni Egun won ni Egu ni awon n je.
Nibi ayajo odun Egu to waye l'Ojobo to koja yii ni alaga igbimo to risi ajodun yii, Ogbeni Abayomi Semako Hunye ti gbe so fun awon oniroyin nipa atunse si asipe oruko won.
Awon omo eya Egu eleyii ti won wa ni Ipinle Ogun ati Eko ni alaga ayeye so wi pe aiwalojukan awon tunbo mu adiku agbara ba awon eya Egu. Gege bi oro re, oni egbe omo Egu lapapo dale nipa iranlowo fun ara eni ati lati mu idagbasoke ba agbegbe ti onikaluku ba wa lai fi toro oselu se.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment