Bi owo ba ti de, ako oge sise di irorun. Mercy Aigbe naa ti wo awokose awon agba oserebirin bi Ini Edo ati Genevieve Nnaji ti won n fowo soge wiwo pelu bi oun naa se lo ko owo ra baagi apamo "Chanel Lego clutch bag" eleyii ti owo re to egberun mewaa owo dola ile Amerika (N1.55million).
Sugbon sa, awon kan so wi pe won ti n se adamodi iru baagi yii kan naa ni ile Naijeria eleyii ti owo re ko ju nnkan bi egberun marunlelogoji (N45K) owo naira ile wa lo.
Bi baagi yii se ri bakan naa ko je ki enikeni le so iru eyi ti Mercy Aigbe gbe dani gan-an san-ansan.
Home / Amuludun /
Foto
/ Mercy Aigbe Naa Ti N Fara We Awon Iyanlaya Oserebirin Pelu Baagi Oge Egberun Mewaa Owo Dola Ile Amerika
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment