Smiley face

E Ba Wa Foju Agba Wo Aworan Yii.

Mo ri aworan apanilerin yii lori ero ayelukara laipe yii. Aworan naa ko koko ye mi, sugbon igba mo teju moo daradara ni alaye re ye mi kedere.

E joo, se otito ni afihan aworan yii, iro lo n pa ni abi otito?

#NaijaIluOlokikiNla#
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

4 comments:

  1. Hahahahahahaha. Omuti gbagbe ise. Oju to ye ko fi riran lo ti fi mu igo bia meje pelu tajutaju meta. O fi oju ona sile ja sinu ko.

    ReplyDelete
  2. O ga ooo, bi omugo(olotin) ile America se n rin ni ologbon (eni ti o mu otin) ile naijeria se n ri. E ko wo le yii ko wa ooo? Oro naa ko ti ye mi ooo

    ReplyDelete
  3. yusuff sheriffdeen6 January 2014 at 16:45

    Ko si iro ninu aworan yi rara,otitu ni

    ReplyDelete
  4. Nawa for naija. I can't laugh jare

    ReplyDelete