Smiley face

Omobirin Sorosoro Ori Redio Ati Telifisan Ti Lo So Yigi Ni Kootu Lai Pariwo



Omobirin sorosoro ori redio ati telifisan,Toke Makinwa se igbeyawo bonkele pelu ololufe re. Bi o ti le je wi pe oun gan-an se e lalaye wi pe pajawiri ni igbeyawo naa  je fun oun (omobrin naa tun yan wi pe kii se wi pe oun ti loyun ni oun fi se igbeyawo kiakia bee).

Gege bi oro re, oni awon kan lo so ara awon po ni kootu ijoba lasan ni labe ilana ofin. O ni ojo ariya si n bo lona eleyii ti oun yoo pe gbogbo ore ati ojulumo lati wa je iresi gbigbona ati waani tutu pupa oloju resuresu.
 
 

 


 

 









Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment