
Awon ọmọ ẹgbẹ ajijangbara esin Islam kan ni ilu Syria ti oruko won n je Islamist State in Iraq and Syria ti se idajo ole kan ti won mu, eleyii ti ole naa gba wi pe oun jẹbi esun ole ti won fi kan-an nipa gige ọwọ́ rẹ danu gẹgẹ bi ofin Sharia. Ẹ tun le ka iroyin naa siwaju gẹgẹ bi ile ise iroyin Fox se se atejade re [NIBI]
0 comments:
Post a Comment