Smiley face

Wizkid Ati Awon Obi Rẹ Lode Ariya Pẹlu Faaji


Sebi adura gbogbo awon abiyamọ aye ni wi pe awon ọmọ won yan ki won si yanju. Lonii, Ayọ tẹlẹ awon obi rẹ mejeeji lo se faaji lode ariya. Ọmọ Balogun si se apejuwe awon obi rẹ gẹgẹ ibẹẹrẹ ati opin ohun gbogbo  ti oun da lonii. Lọjọ to le koko ati ọjọ to ku diẹ kaato, sebi obi ẹni naa ni obi ẹni. 


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment