Billboard Magazine ti kede Beyonce gege bi olorin alawo dudu to pawo ju lo lagbaye lati igba yii wa. Eleyii ni won kede latari iyide orin ati ijo re, Mrs Carter Show World Tour nibi to ti pawo bi $212M. Tikeeti iworan re to ta si din die ni nnkan bi milionu meji lapapo.
Aseyori yii mu gba irawo lowo Micheal Jackson ti o ti n gbe Ade irawo eniyan dudu to pawo ju lode orin kiko nigbogbo agbaye.
Osupa oba orin lo so wi pe to ba je okunrin ni, Baba-Baba ni won maa n pe won. To ba je obirin ni, iyanlaya ni won je. Lai pariwo soke, Beyonce ti di Iyanlaya Orin Erujeje.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment