Awon omo ibeji ti ori won lepo yii ni dokita so wi pe opolo meji ni won ni sugbon ori kan soso lo wa lorun kan soso.
Awon omo yii ti lo ojo mokanla laye bayii, akiyesi dokita si ni wi pe ti won ba le lo ose marun-un sii laye a je wi pe o seese ki won ye.
Ati igba ti won ti wa ninu oyun ni awon dokita ti se akiyesi bi awon omo naa se lepo, sugbon iya won ko lati seyun won
0 comments:
Post a Comment