Aro yii ni Otunba Kola Olootu se afihan aworan ara re nikete to setan ni baluwe nimura fun ayeye ifilole awo orin tuntun Femi Solar.
Nibayii, Gomina egbe sorosoro ni Ipinle Oyo ti wo ankara egbejoda lati lo ba Femi Solar ko awo re tuntun to pe ni "Grace" jade bi omo tuntun eleyii ti yoo waye ni ilu Ibadan lonii.
0 comments:
Post a Comment