O ti to ojo meta ti mo ti n jayin si nipa omobirin ti oruko re n je Kim Kardashian to je aya gbajugbaja onkorin ile Amerika, Kanye West.
Gege bi mo ti so saaju, ilu France naa ni won si wa eleyii to wa lara igbaradi eto igbeyawo won to n bo lona.[E le ka iroyin naa nibi] Bi eniyan ko ba mo Kim tele pelu ede to pe ninu iroyin ti mo koko so nibi to ti pede wi pe Furo Mi Setan Fun Igbeyawo Alarinrin, eniyan o sebi boya ko mo okunrin ri ni. Sugbon lonii ni ilu France, won gbe omo won, omo osu mokanla ti oruko re n je North yide ilu Pariisi. ![]() |
Km ati North |
0 comments:
Post a Comment