Gege Bi oro Orlando Owoh, opo awon eniyan ni won se 'Bigimaanu' lode sugbon ise owo won ko se e ri. Opolopo omoge onibadi oge, ibadi aran ati awon ti ibadi won dabi ile tiiro lo je wi pe ogbon orisiirisii ni won da la ti le ba igba mu. Sebi omo taye n bi laye pon, kaka nla ti won pe ni ukwu lo nigboro nigbogbo omoge fi n wa ogbon lati yodi ti won yoo maa fi gbeja kiri igboro .
Awon kan maa n gun abere yodiyodi, awon kan n lo ike rubber, awon kan si n lo omi acid alagbara lati seda idi okoto. Bi eniyan ba se fe ki idi oun tobi to ni yoo so iru eroja ti won yoo ba ko sinu idi re ki 'isu' re le ta sita daada. Orisiirisii awon dokita ni won si ti bere iru ise oge yii sugbon awon ayederu lopo ninu won.
Awon omoge onibadi aran ko leta si Olayemi Oniroyin. Won ni tori awon okunrin la won fi n se gbogbo ohun ti awon se. Won ni awon okunrin ode oni feran 'aridimu' to kun fofo to le kaka bi odiakah. Mmmmmmh!
Oge won kii pe titi nitori to ba ya yala ki idi won maa somi tabi ki ike ti won gbe sinu idi won bere si ni sun kuro loju ibi to ye ko duro si. Awon omi kemika buruku ti won fi n se awon rubber ti won ko sidi won yoo si bere si ni jo, lati ibe lo omi kemika buruku naa yoo si maa san kaakiri ara awon. Awo(skin) idi won yoo si maa dipeta bi adete, alaafia ko si ni si fun ago ara won mo ni awon akoko yii.
E ti ri idi orisiirisii to rewa, Nibayii, mo fe ke e ri THE END pupo ninu awon ti won se iru oge idi nla yii.
Mo fe ki e fi eyi kogbon, mo si royin lati kede fun gbogbo awon omoge asiko wi pe ki won ni itelorun pelu ohun ti Olorun oba ba fun won. Ki e to lo. Mo fe ki e tun ka itan omobirin kan to ba aye ara re je nitori oge aseju. E le ka itan naa [NIBI].
To ba je dandan fun awon obirin lati fidi soge fun awon okunrin, won le lo iru foomu to wa ni isale yii. Ko ku seni to fe mo boya foomu ni tabi idi gidi a fi ti won ba tu iru eni bee wo laso. E maa gbagbe itan ti mo ni ke e ka. Itan naa ni YII.
0 comments:
Post a Comment