Ilu China ti fi ipa tuntun sile lagbaye pelu bi awon oloyun bi ogoruun marun-un ati marun (505) se gbarijo si oju kan lati se idaraya eleyii ti ko sele ri nibikibi lagbaye.
Asoju iwe akosile manigbagbe kayeefi ti a mo si Guinness Book wa nibi idaraya naa lati jeri sii. Lara eri won ni wi pe gbogbo awon obirin naa ni won loyun eleyii to si kere ju ni oyun ose mejila.
0 comments:
Post a Comment