Omidan Sahhara ti won bi gege bi okunrin sugbon to yi iseda ara re pada si obirin ti ki Ogbeni Nigeria, Emmanuel Ikubese ku ori ire pelu bi o se se ipo keji ninu idije Ogbeni Agbaye to waye ni ilu Oba lose to koja yii.
E le ka siwaju sii nipa Omidan Sahhara [NIBI]
0 comments:
Post a Comment