Ilu London ni Wizkid si wa, mo sebi e ko gbagbe. Ohun ti Ibrahim fi n se faaji ni yii losan awe Ramadan.
Pupo awon ololufe re ti won ka gbana mo lowo ni inu won ko dun si i, won ni o si kere lati bere aye re pelu igbo ni mimu. 'Eni aye ba n ye ko maa sora, ayo ni akere fi kan nitan,' ni asa ti won da fun-un.
Sebi meji ni ile aye, nibi ti awon kan ti ni ko dara ni awon kan ti ni 'well done, omo gidi to jaye ju'.
0 comments:
Post a Comment