Smiley face

Awon Aworan Meta Ti Ojo Abameta Wa Ni Yii

Aworan Kinni: Saka ati awon omo agbaboolu Nigeria nigba kan ri. Awon omo olorin meji naa wa ninu won. Se boolu tun ni Saka fe maa fi pawo bayii ni?


Aworan Keji: Ronke Oshodi n mura lati lo si ile iwe. Ohun to je keyeefi fun mi ju ni bo se ko gbogbo 'Oshodi oke' re sinu aso uniform re ti ko si ta sita bi isu Abuja. E o ri wi pe osere naa gbiyanju gidi gan.
Aworan Keta: Iya Ofili ra bata ofili. #lobatan.


E ku ataaro. Mo lero wi pe eni ojo to dara.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment