Smiley face

Awon Foto Lati Ibi Ayeye Notting Hill Carnival Ti N Lo Lowo Ni Ilu London Ati Ami Eye Ti Won Fun Dayo Amusa

   
Nibi ti awon kan ti n jo, awon kan mu otin yoo, Notting Hill Carnival ni gbogbo re ti n waye ni ilu London.
Bakan naa ni mo tun se afikun foto Dayo Amusa nibi to ti gba ami eye Diamond Special Recognition Award ni ilu London.


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment