Okan ninu awon oludije fun ipo Aare ilu Brazil, Eduardo
Campos ti je Olorun nipe losan oni nigba ti baalu jeeti re jabo loju
ofurufu ti gbogbo re si jona wuruwuru.
Campos, eni odun mokandinlaadota (49) la gbo wi pe nnkan yiwo mo awako baalu re lowo latari oju ojo ti ko dara.
Goosu
ila-oorun Santos ni baalu okunrin to ti fi igba kan je gomina
Pernambuco jabo si pelu awon eniyan mii ti won ku sibe isele buruku naa.
Ijamba buruku sele ni ilu Brazil, oludije fun ipo aare segbe sinu ijamba oko ofurufu.
Ki Oluwa oba Yaradu ba wa da owo ibi duro.
0 comments:
Post a Comment