Aipe yii ni Rukky Sanda, okan lara awon osere Nollywood ti Nigeria se ojo ibi alarinrin. Lara awon eniyan ti won wa sibi ode ariya naa ni Osita Iheme.
Osita ti lomi lara ju ti tele lo. Ireti wa si ni wi pe oun naa yoo gbe iyawo sile laipe gege bi ekeji re, Chinedu se se.
0 comments:
Post a Comment