Dafiidi omo Adeleke ti wa ni ilu Abidjan bayii nibi taa ti
lero wi pe yoo ti maa pate orin alujo fun awon onifaaji omo jayejaye.
Sugbon kete ti Davido wo ilu Abidjan, ile awon omo alainiya ati baba lo gba lo lati lo se itore aanu.
Sebi oro bibeli ni wi pe enikeni ti iwo ba nipa lati se iranlowo fun, ohun naa ni enikeji re, tooju re.
0 comments:
Post a Comment