Awon ebi awon eniyan ti arun ebola mu ti ko awon alaisan won sile latari iberu ki awon naa ma se agbako arun buruku naa. Awon eniyan yii ku sinu inira nla loju titi pelu bi eje se n jade leti ati enu won lai ri eni gbe won lo si osibitu.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment