Smiley face

Oba Wura Ati Fadaka N Jaye Bi Oba Gidi

Ayodeji Balogun ti pada silu London. Bo se wo ilu London ni omo naa lo ra goolu ati fadaka ti owo won n lo bi egberun lona ogun poun (£20, 000) eleyii to din die ni milion marun-un owo naira ile wa.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment