Smiley face

Se Oko Mide Funmi-Martins Ni Ka Ki Ni Abi Iyawo?

Igbagbo awon eniyan ni wi pe ti oyinbo alawo funfun ba lo nnkan ku, bi moto tabi aso, awon nnkan bee si se lo fun eniyan dudu.

Ti eniyan dudu ba lo moto ku, iru moto bee kii se lo fun enikeni mo nitori alopa ni awon eniyan dudu n lo nnkan.



Bi okunrin mii ba lo obirin bayii, leyin odun meji si meta obirin naa yoo ti di radarada. Sugbon okunrin bi Afeez Owo Seriki Olopolo ko pe meji pelu bi o se n fi opolo pipe lo aya re yato si ilokulo ti awon okunrin mii n lo iyawo won.

Ewa Mide o baje, ewa naa tun bo n posi ni. Se a le gba wi pe Afeez lo n se itoju iyawo re to fi dara bi eleyii abi Mide gangan ni i tun ara re se?

Se Oko Mide Funmi-Martins Ni Ka Ki Ni Abi Iyawo?


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment