Awon egbe APC ti Ipinle Ekiti ti bere si ni leri wi pe awon ko ni gba ki Gomina ti ara ilu dibo yan, Ogbeni Ayodele Fayose de ipo isakoso Ipinle Ekiti. Siamaanu egbe APC ti ipinle naa oloye Jide Awe lo soro yii. O ni ajoji ni egbe PDP, awon ko si ni fun won laye rara.
"This is our land. The land of the progressives, We won't allow any stranger to take it from us." - Jide Awe.
Niwon igba to ti je wi pe ofe lohun. Akowekowura fun Ayodele Fayose, Ogbeni Idowu Adelusi ti fi ede awon omo orita ranse ohun pada si egbe APC.
O ni, 'e so fun won ki won gbagbe yen, ki won stop sebee. Eshin funfun to siwaju ti gba ipo kinni, ewo loshisko ti won ba kiri gan-an?
E je gba kadara ki e maa ba gba kodoro. Awon eniyan ti dibo fun Fayose, dandan si ni ki Ipinle Ekiti tesiwaju. E je so fun won ki won ma lo ra 'CEltel'.
Tori ti won ba ra Celtel dandan ni ki won pada te o'.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment