Smiley face

Aworan Omobirin Ti n Ba Kinihun Sore Timotimo

Awon eniyan kan so wi pe omo eranko wulo nigba mii ju omo eniyan lo. Won ni ti ore ba pe, omo eniyan le gbagbe sugbon aja kii gbagbe oloore. Sebi iyen aja, se bii kinihun ololaaju wa ni? Won ni bakan naa ni gbogbo omo eranko ri, ati aja, ati kinihun, okan naa ni gbogbo won ninu wa ati ise won.

Ironu sori agba kodo!



Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment