Smiley face

"Mo Le So Wi Pe Iyawo Mi Ni Ilosiwaju Aseyori Mi'- Joseph Yobo

Joseph Yobo to je okan lara awon omo agbaboolu Nigeria ti se apejuwe Adaeze to je iyawo re gege bi ilosiwaju aseyori re. Oro yii lo so fun awon Oniroyin latari ile tuntun bi igba milionu owo naira to ko ni oruko iyawo re lati fi dupe atileyin to n se fun un nigba gbogbo.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment