Oni ni ojo ibi Solomon Olugbenga Motimoke ti gbgbo eniyan mo si Yatty. Ilu Amerika naa ni Yatty si wa nibi to ti n jaye bi oba Lamidi leyin igba ti won ti kuro leyin Yinka Ayefele ni ilu Yankee. A ki omo olojo ibi ku ori ire. Igba odun, odun kan ni.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment