Smiley face

Won Ti Dajo Iku Fun Omo Nigeria Ni Ilu Malaysia

Ile ejo to gaju ni ilu Malaysia ti dajo iku fun Abuchi Ngwoke, eni odun marunlelogbon (35) ni ilu Malaysia pelu esun wi pe o gbe ogun oloro wo ilu naa.

Odun 2012 ni won mu Abuchi nigba to wo ilu Malaysia lati Nigeria, ayewo awon onibode si fi han wa wi pe o gbe ogun oloro ti iwon re din die ni oodunrun kilogiramu sinu ikun.

Ojo Isegun [25-11-14] ni won da ejo naa.

E joo,  bawo ni won se n gbe ogun oloro pamo sinu ikun? (Ibeere Jambu) Erkk.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment