Senator Iyiola Omisore to je okan lara awon oludije ninu eto idibo gomina to waye ni Ipinle Osun ti kegbajari wi pe awon onimakaruru kan ti n pete-pero lati gba emi ohun. Oro yii lo so jade lati enu agbenuso re fun eka iroyin ati ikede, Ogbeni Victor Oriola.
"We are constrained to inform the general public, especially the security agents that we have uncovered plots
to assassinate Senator Iyiola Omisore in order to cover up the electoral heist perpetrated on August 9, 2014." - Victor Oriola
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment