Smiley face

Won Ti Ko Kaadi Akoko Ipe Lori Foonu Buhari Wole Silu Nigeria

Egbe APC ti setan lati maa pin kaadi akoko ipe lori foonu fun awon oludibo lati dibo fun Muhammadu Buhari lodun to n bo. O da bi e ni wi pe iresi ti n su awon omo Nigeria, Tinubu yaa wa ogbon mii da ni kiakika. Erkk
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment