Igbakeji oludije fun ipo Aare labe egbe oselu APC, Yemi Osibanjo ti lo feyinti awon iyaloja ati babalaje Ipinle Eko nipa ti eto idibo si ipo Aare eleyii ti yoo waye losu keji odun ti n bo.
Laipe, igbakeji Muhammadu Buhari yoo yoju si awon ipinle to ku naa ni ile kaaro-o-jiire.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment