Smiley face

Abiamo Gbe Omo Sinu Baagi Ni Ilu China


Asa tuntun tun gbode ni ilu China pelu bi Xue Hsueh eni odun merindinlogbon (26) se n fi baagi gbe omo re kiri lai se omo aja. Sugbon sa, kete ti aworan naa ti de ori ero ayelukara ni gbogbo eniyan ti bere si ni naka abuku si iya omo naa. Awijare Xue Hsueh naa ni wi pe kii se wi pe omo naa lo igba pipe ninu baagi naa, o ni igba die lasan ni oun fi gbe sinu baagi ti won ri lori ayelukara.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment