Awon eniyan bi marunlelọgbọn (35) ni won ti tẹ pa bayii ni ilu Shanghai to wa ni China nigba ti enikan fọn owó ayederu kan soke ti gbogbo èrò si suru bo owó naa ni gbagede ti awon eniyan ti n yọ ayọ odun tuntun. Awon eniyan bi mejilelogoji (42) mii lo tun fara pa yẹlẹyẹlẹ ti won ti gbe lo si osibitu fun itoju.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment