Smiley face

Buhari Fesi Lori Ipolowo Aare Jonathan Ti Ayo Fayose Se Sinu Iwe Iroyin Punch Ti Ile Naijeria

Ayo Fayose se agbeteru ipolowo sinu iwe iroyin PUNCH lonii lati fi se ipolongo fun Aare Goodluck Jonathan. Ona ti won gba se ipolowo naa bi Muhammadu Buhari ninu gidi gan-an. Okunrin naa ti lo si ori ero twitter re lati lo faraki gidigidi gan-an.




 E pade mi lori twitter loju opo @OlayemiOniroyin fun awon iroyin to n gbona felifeli.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment