Amber Rose to je okan lara awon irawo olorin ilu Amerika ni
awon kan ti se apejuwe awon aworan re to kun ori ero ayelujara gege bi forifori
fun oko re atijo, Wiz Khalifa to ko sile. Laipe yii naa
ni oko re naa ya foto pelu omoge onibadiran kan to tun je onise oge eleyii ti oun
naa gbe aworan naa sori ayelujara.
Ewa Amber Rose eleyii to tun un bo n
peleke sii lojoojumo ti mu gbogbo eniyan maa da Wiz Khalifa
lebi pelu bo se je ki iyawo re bo mo o lowo.
To ba je wi pe ni ilu Miami ni, iroyin Amber
Rose lo gba igboro kan. Awon 'dukia' ti omo naa n gbe kiri igboro ko derun rara.
Awon ohun ti omobirin naa pate sori ate koja ohun ti eniyan le
fenu royin tan. O leku!
0 comments:
Post a Comment