Amber Rose, okan lara awon omo olorin ilu Amerika ti da gobe sile bayii lori ero ayelujara ni kete to se afihan awon aworan re faye ri. Omobirin yii eleyii ti ipinya ti de ba oun ati oko re, Wiz Khalifa tele ni awon eniyan ti pada n so kiri wi pe oko omobirin naa so eran jobojobo nu pelu ija to waya laarin won.
Kini awon eniyan ri ti won fi n pe Amber Rose ni eran jobojobo?
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment