Smiley face

Won Se Igbeyawo Alarinrin Ninu Poosi Ni Ilu Thailand

Bayii la n se ni ile wa, eewo ibo mii ni. Awon toko-taya kan ti se igbeyawo alarinrin eleyii ti won se ninu poosi niwaju orisa Takien to wa Nonthaburi ni ilu Thailand.
Eyin iyawo ko ni meni oo
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

1 comments: