Smiley face

"Aimoye Owo Dollar Ni Mo N Na Lori Awọ Mi To Fin Da Bi Egbin" - Dayo Amusa

Ise tiata ko yato si ise oge sise. Boya eyi ni awon onise tiata ki fi ko iyekiye lati na lori aso wiwo, irun sise ati ti tun ara awon se lọjọ. Awon nnkan wonyii nii se pelu bi won se n rise gba lagbo amuludun. Bakan naa ni omo se sori lodo Dayo Amusa nigba to n so wi pe aimoye owo ti ko see maa so jade ni oun na lati tun ra se.

Iyabo Ojo ati Dayo

K1 ati Dayo

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment