COSSY ORJIAKOR, gbajugbaja oserebirin onisinima onihoho ati onise nabi ti tun gbe aworan re tuntun jade faye ri nibi o ti n polowo awon oja re to se koko. Sebi awon Yoruba naa ni won wi pe ipolowo oja lagunmo owo, Onikaluko naa lo si n wa ona ti oja re yoo fi ta warawara. Ninu aworan tuntun naa, COSSY taari aya sita ki won le ri ọjọ iwaju to dara bakan naa lo tun garu ẹyin ki won le wo apoti ijoko rẹ bo se ga to. Atiwaju, ateyin; nnkan ki sese raago. Eniyan to ba kanludo lo leroyin. Eniyan to ba laya lo le we okun eyi ja. Eni ti o ba mọwe to ba kan lu odo etile, ori le ko won yo. Eniyan ti o ba mowe to ba kan lu omi okun nla, Onitoun wo gẹlẹdẹ daran naa nu-un ni. #Lobatan
Olayemi Oniroyin ni mo n jẹ, Olorun mo jẹ n royin ti o ko ba mi.
0 comments:
Post a Comment