Iwadii ti a se fi ye wa wi pe, orisii orin kan ti wa saaju ti n je Olalomi eleyii ti ko si ipa re mo laye ode oni. Awon kan ni, ni...
Read More
Home / Akoni
Showing posts with label Akoni. Show all posts
Showing posts with label Akoni. Show all posts

Itan igbesi aye Ligali Mukaiba olorin apala ilu Epe 1
Ligali Mukaiba Iwadii to fese mule fi ye wa daju saka wi pe, awon olorin ti n sise iroyin ki orisii awon eniyan kan ti won je oniroyi...
Read More

Odun kerin leyin ti irawo Bisi Komolafe jabo loju orun
Bisi Komolafe Ti ba n ranti eni ti n be laye, awon Yoruba ni ko buru taa ba tun seranti eni ti n be lajule orun. Sebi kosi eni ti k...
Read More

Ayajo oni ni Sani Abacha ku lodun 1998
Oni ni i sami ayajọ ti Sani Abacha jade laye, 08-06-1998; nnkna bi odun mejidinlogun (18) seyin. Bi o tilẹ jẹ wi pe, atejade lati...
Read More

To ba je wi pe Samuel Okwaraji n be laye ni...
To ba je wi pe Samuel Okwaraji n be laye, o ni yii ni ko ba pe omo odun mejilelaadota (52). Sugbon iku seka, iku doro, iku o je ki Okwar...
Read More
Subscribe to:
Posts
(
Atom
)