Hubert Ogunde: Ohun tí àwọn onsọ̀tàn sọ nípa ìbẹ̀rẹ̀ tíátà Nigeria Olayemi Oniroyin 9/26/2019 10:58:00 am Add Comment Edit Hubert Ogunde Ko ̀ si ́ bi ́ a s ̣ e fe ̣ ki ́ Ì ba ̀ da ̀ n la ́ i ̀ me ̣́ nu ba àru ̀ n Ìba ̀ da ̀ n; sebi ́ wo ̣́ n... Read More
Wizkid bale ọba jẹ nílùú London! Olayemi Oniroyin 5/28/2018 10:06:00 am Add Comment Edit Omilẹgbẹ èrò bí ọjọ́ àjíǹde ni wọn ya wo 02 Arena láti wá wòran Ayodeji ọmọ ológo dídán. Igba àkọ́kọ́ ni yìí nílùú London ti onkorin ilé adú... Read More
Ọkùnrin ní má fi oyún inú mi bí - @LindaIkeji Olayemi Oniroyin 5/21/2018 10:55:00 am Add Comment Edit "Mi ò lè pa ayọ̀ yìí mora mọ. Ìdùnnú mi lo jẹ láti kéde rẹ fún yín wí pé, àkọ́bí ọmọ mi kò ní pẹ́ de ba mi lálejò ni nǹkan bí oṣù kan s... Read More
"Ojú tí Nìyí, Toyin Abraham ti pàdé ọkọ tuntun oloriire" - Àwọn tí Toyin fò fáyọ̀ Olayemi Oniroyin 5/21/2018 10:42:00 am Add Comment Edit "Ojú ti Nìyí aronipin! " Awọn olólùfẹ́ Toyin Abraham ti gbogbo ènìyàn mọ sì Toyin Aimakhu tẹ́lẹ̀ tí ń bá yọ báyìí pẹ̀lú bi òṣerébì... Read More
Foto ètò ìsìnkú Aisha Abimbola nílùú Canada Olayemi Oniroyin 5/18/2018 10:21:00 am Add Comment Edit Read More
Ìrántí ọdún kan Moji Olaiya wáyé lẹ́yìn ìsìnkú Aisha Abimbola Olayemi Oniroyin 5/17/2018 11:38:00 pm Add Comment Edit Moji Olaiya tí pé ọdún kan báyìí. Aisha Abimbola lọ ṣẹ̀ṣẹ̀ bẹ̀rẹ̀ ìrìnàjò tiẹ̀ sóde ọ̀run ni. Ta wá ni ènìyàn tí kò ní kú? Àdúrà wa kan ni w... Read More
Ọ̀rọ̀ tí Aisha Abimbola sọ kẹyin lórí whatsapp kó to kú ní yìí Olayemi Oniroyin 5/16/2018 08:40:00 pm Add Comment Edit Ali Baba, ogbontarigi alawada ilẹ̀ Nàìjíríà tí ṣe àfihàn itakurọsọ to wáyé kẹyin láàárín òun àti olóògbé Aisha Abimbola. Nínú itakurọsọ orí... Read More
Ìgbéyàwó òṣerébìnrin onitia míì tí tú ká? Ohun tí Ìrètí Osayemi sọ nípa ìdílẹ̀ rẹ ni yìí Olayemi Oniroyin 5/16/2018 07:31:00 pm Add Comment Edit Orisirisi ahesọ ọ̀rọ̀ lọ tí kún ìgboro báyìí wí pé òṣerébìnrin Ìrètí Osayemi náà tí pàdánù ìgbéyàwó rẹ pẹlu Bakare Adeoye. Ṣùgbọ́n sá, àwọn... Read More
"Odunlade ò rí pátá mi rí" - Eniola Ajao Olayemi Oniroyin 5/16/2018 02:37:00 pm Add Comment Edit Eniola Ajaola tí sọ ọ kedere wí pé kò sí ajosepo lọkọlaya láàárín òun àti Odunlade Adekola. Nínú ifọrọwero pẹ̀lú òṣerébìnrin yìí ló ti se à... Read More
Aisha Abimbola (Ọmọge Campus) tí kọjá sọ́run nílùú Canada Olayemi Oniroyin 5/16/2018 01:54:00 pm Add Comment Edit Òṣerébìnrin ilẹ̀ Nàìjíríà, Aishat Abimbola tí gbogbo ènìyàn mo sì ọmọge Campus tí papoda lọ́jọ́ mẹẹdogun oṣù karùn-ún ọdún 2018. Òṣeré náà ... Read More