"Oruko mi ni Funke Akindele aya Bello" - Jenifa Olayemi Oniroyin 8/28/2016 10:48:00 pm Add Comment Edit Leyin aimoye awon aheso iroyin to ti n suyo nipa wi pe Funke Akindele ti se igbeyawo bonkele pelu Abdulrasheed Bello ti opolopo mo si ... Read More
Sanyeri ra moto tuntun fun iyawo re Olayemi Oniroyin 8/24/2016 12:33:00 pm Add Comment Edit Ogbontarigi alawada onisima agbelewo, Olaniyi Afonja omo iya eleyin niluu Oyo, ti gbogbo eniyan mo si Sanyeri lagbo wi pe o ti ra oko tu... Read More
"Supamaanu lọkọ mi ooo" Irawo oserebirin onitiata lo so bẹẹ Olayemi Oniroyin 8/21/2016 08:19:00 pm Add Comment Edit Kosi ohun to dun bi ki orekelewa obirin ri okunrin gidi fẹ. Ifokanbale nla si ni fun okunrin to ba pade obirin alalubarika to yaayi. ... Read More
Adekunle Gold: Ijinle orin lagbara lati gba emi la lowo iparun Olayemi Oniroyin 8/20/2016 09:53:00 pm Add Comment Edit Adekunle Gold Agbara orin ko lounka, eleyii to le sisẹ fun iwosan, bakan naa ni orin le gba emi eniyan la lowo iparun. O wa lọwọ bi o... Read More
Beautiful Nubia: IWA Olayemi Oniroyin 8/15/2016 03:26:00 pm Add Comment Edit Fun anfaani awon to nife si orin to kun fun ogbon ati arojinle to nipon, eyi ni lati fi to yin leti wi pe, Segun Akinlolu, ti gbo eniya... Read More