Fidio orin Bazooka ti jade lati owo Inspirashn, Grandpa Awon Girls Olayemi Oniroyin 9/10/2016 12:00:00 pm Add Comment Edit Bi o ba logbon orin gidi fi pamo lojo ti Inspirashn ba n korin. Orin ju orin lo, a jurawa lo ijakadi ko. O wu Edumare lo se ori ewa fakuko... Read More
Awon omo ole ka Basketmouth mole loru oganjo Olayemi Oniroyin 9/09/2016 07:24:00 am Add Comment Edit Oladeji Kehinde Nǹkan ò s̩e̩nu re̩ fún gbajúmó̩ aláwàdà náà, Bright Okpocha, e̩ni tí gbogbo èèyàn mò̩ sí Basketmouth, ... Read More
Oba orin Saheed Osupa ti bale siluu Jamani Olayemi Oniroyin 9/08/2016 09:40:00 pm Add Comment Edit O daju wi pe odun ileya to n bo yii, ki i se ilu Naija ni Saheed Osupa yoo ti se e pelu bo se bere iyide orin ka re si awon ilu okee... Read More
Oyekunle Azeez lori eto Erebente Olayemi Oniroyin 9/07/2016 01:01:00 pm Add Comment Edit Orisun: Oyekunle Azeez Proff/Facebook Oyekunle Azeez Proff Oyekunle Azeez Proff Read More
Awo orin tuntun Saheed Osupa: NEW DAWN Olayemi Oniroyin 9/05/2016 11:28:00 pm Add Comment Edit Oba orin Saheed Osupa ti kede lati gbe awo orin tuntun re, New Dawn, jade saaju ki odun ileya to wole de. E ku oju lona! Read More