[Fidio] Alujo Oba Orin Saheed Osupa niluu Italy Olayemi Oniroyin 10/01/2016 12:17:00 pm Add Comment Edit Saheed Osupa se afihan okan ninu awon ere re ni Napoli to wa ni orileede Italy ati bo se n se faaji re kiri igboro. Awon fidio naa ni y... Read More
Egbon Saheed Osupa sojo ibi lonii ayajo ominira Olayemi Oniroyin 10/01/2016 12:11:00 pm Add Comment Edit Ẹgbọn Oba Orin Saheed Osupa, Latty Libra Okunola, le lodun lonii to je ayajo ọjọ ominira Naijiria. Osupa ọba orin lo kede eleyii ni... Read More
" A ti bale siluu France" Saheed Osupa oba orin Olayemi Oniroyin 9/24/2016 12:04:00 pm Add Comment Edit Ilu Italy ni Saheed Osupa ti gbera wo ilu France, eleyii to kede nigba to wa ni papako ofurufu ilu Italy. Foto Saheed nigba to fe gber... Read More
Alujo King Saheed Osupa fe wole siluu Sweden Olayemi Oniroyin 9/23/2016 10:13:00 pm Add Comment Edit Fun awon ololufee King Saheed Osupa niluu Sweden, asiko ni yii lati fi igbadun sayo pelu bi Oba Orin yoo se ma pate alujo ni Gothenburg... Read More
Atiku se alaye pataki orin Sunny Ade lodun 1960 lagbo awon onifaaji Olayemi Oniroyin 9/23/2016 06:06:00 pm Add Comment Edit Gege bi oro awon Yoruba, won ni arugbo soge ri, akisa logba ri. Yoruba naa lo wi pe, ori taa fi sewe ki i kuro lorun eni ta a ba dagbala... Read More